AddToAny

Asegbolu Matched Content

Search

Looped Slider

Everybody has the potential to be great . Never look downward ,never look straight but always look upward for divine upliftments and achievements

Related Posts Plugin for WordPress, Blogger...
Powered by Blogger.
Email Newsletter

Subscribe to our newsletter to get the latest updates to your inbox. ;-)

Your email address is safe with us!

ADURA. ALUFABETI YORUBA FUN GBOGBO WA.

A-Alaafia fun o.
B-Buburu kan ki yoo subu lu o.
D-Dugbedugbe ibanuje ko ni ja le o l'ori.
E-Eemo orun apadi ko ni mo ile re.
E-Ekun, ose ko ni je tire.
F-Funfun aye re ko ni dibaje.
G-Gunnungun ki ku l'ewe, wa dagba d'arugbo.
GB- Gbogbo idawole re a y'ori si rere.
H-Hausa,Yoruba,Ibo,gbogbo eya ati eniyan kaakiri agbaye ni yo koju si o se o loore.
I-Iwaju, iwaju l'opa ebiti re yo ma re si.
J-Jijade re, wiwole re, o ni k'agbako.
K-Kukuru abi giga osi ati ise ko ni je tire.
L-Loniloni wa r'aanu gba.
M-Manamana ati ara Olorun yoo tu awon ota re ka.
N-Naira, Euro, Dola, Poun,Yen,Yuan,gbogbo owo ati oro kaakiri agbaye pelu omo alalubarika ati alaafia yoo mu o l'ore, won o si fi ile re se ibugbe..
O-Ojurere ati aanu yoo ma to o leyin ni ojo aye re gbogbo.
O-Ojo ola re a dara.
P-Panpe aye o ni mu o t'omotomo.
R-Rere ni agogo aye re o ma lu nigbagbogbo.
S-Suuru pelu itelorun ninu oro at'alaafia yoo ba o kale.
S-Sugbon ati abawon aye re ti poora loni.
T-Tomotomo, t'ebitebi, t'iletile o ni d'ero eyin.
U-U ki s'awati lede Ijesha; a o ni fi o s'awati laarin awon eniyan uyi (iyi),eye, ulosiwaju(ilosiwaju), userere(iserere),ati ubukun(ibunkun).
W-Wa ri ba ti se, wa r'ona gbe gba.
Y-Yara ibunkun, ire, ati ayo ailopin loo ma gbe titi ojo aye re. Ka sun layo ooo. AMIN.

Auto relaxed

About

Add Your Gadget Here

Entertainment

Latest News

Entertainment

Subscribe Via Email

Subscribe to our newsletter to get the latest updates to your inbox. ;-)

Your email address is safe with us!

(C) Copyright by Just Sharing Thoughts Worth Sharing
Wordpress Theme by QualityWP | Conveted to Blogger Template by ThemeLib.com

Search This Blog

Pages

ADURA. ALUFABETI YORUBA FUN GBOGBO WA.

A-Alaafia fun o.
B-Buburu kan ki yoo subu lu o.
D-Dugbedugbe ibanuje ko ni ja le o l'ori.
E-Eemo orun apadi ko ni mo ile re.
E-Ekun, ose ko ni je tire.
F-Funfun aye re ko ni dibaje.
G-Gunnungun ki ku l'ewe, wa dagba d'arugbo.
GB- Gbogbo idawole re a y'ori si rere.
H-Hausa,Yoruba,Ibo,gbogbo eya ati eniyan kaakiri agbaye ni yo koju si o se o loore.
I-Iwaju, iwaju l'opa ebiti re yo ma re si.
J-Jijade re, wiwole re, o ni k'agbako.
K-Kukuru abi giga osi ati ise ko ni je tire.
L-Loniloni wa r'aanu gba.
M-Manamana ati ara Olorun yoo tu awon ota re ka.
N-Naira, Euro, Dola, Poun,Yen,Yuan,gbogbo owo ati oro kaakiri agbaye pelu omo alalubarika ati alaafia yoo mu o l'ore, won o si fi ile re se ibugbe..
O-Ojurere ati aanu yoo ma to o leyin ni ojo aye re gbogbo.
O-Ojo ola re a dara.
P-Panpe aye o ni mu o t'omotomo.
R-Rere ni agogo aye re o ma lu nigbagbogbo.
S-Suuru pelu itelorun ninu oro at'alaafia yoo ba o kale.
S-Sugbon ati abawon aye re ti poora loni.
T-Tomotomo, t'ebitebi, t'iletile o ni d'ero eyin.
U-U ki s'awati lede Ijesha; a o ni fi o s'awati laarin awon eniyan uyi (iyi),eye, ulosiwaju(ilosiwaju), userere(iserere),ati ubukun(ibunkun).
W-Wa ri ba ti se, wa r'ona gbe gba.
Y-Yara ibunkun, ire, ati ayo ailopin loo ma gbe titi ojo aye re. Ka sun layo ooo. AMIN.
Share on Google Plus

About Naija Google Blogger

This is a short description in the author block about the author. You edit it by entering text in the "Biographical Info" field in the user admin panel.